(Orúkọ Àpọ́nlé àwọn Obìnrin)
Aya = Wife
Ìyá Afin = Queen (usually older one)
Ayaba = Queen
Yèyé Ọba = Queen mother
Olorì = King's wife
Omidan =Beautiful woman
Ọmọge = Young fashionable woman
Ìyàwó = Wife
Erelú = Female Chief
Ìyálọjà = Market Leader
Ìyálájé = Female title (Successful female entrepreneur)
Ìyálóde = Leader of all women
Yorùbá dùn lédè.
Source: Adeboye Adegbenro
Comment your view, criticism, addition or observation. Let us discuss it.
No comments:
Post a Comment