Sexual communication and lesson before Sex
It says a woman must feed her husband before sex and man should also feed himself. Also, when your stomach is full, it is advisable that wòdí or yẹ̀díwò.
Yoruba Myths teaches wisdom before any other solution.
Ìwòrì wò mí
Ìdí wò mí
Ẹni táa ní níí wo ni
Adíá fun Ìwòrì
Níjó tí ń lọ rèé wòdí
Wọ́n ní kó rúbọ
Bí Ìwòrì ó bàá wòdí
Oúnjẹ níí kún inú ẹ̀
Ayé yẹ ẹ́
Ìwòrì wò mí
Ìdí wò mí
Ẹni táa ní níí wo ni
A díá fún Ìwòrì
Níjọ́ tí ń lọ rèé wòdí
Ìwòrì dákun
Ìwòrì dábọ̀
Èèyán séé wòdí lébi
Ìwòrì dákun
Ìwòrì dábọ̀
This is very important and should be taught to every home. Infact, this is a very big science unknown to many. Eating before sex is very important and eating after sex is good as well.
Why should you have sex in hunger?
Empty stomach is not suitable for sexual intercourse.
Recorded by Ayo Salami.
By Gura Masha. Published 26 Jan, 2020
No comments:
Post a Comment