Òdù de ifá Ìwòrì-Òsá;
Ìná pàpà lò bàlè lò mò róró
Àdìfá fùn Òrùndòjò òmìdàn
Àwòn èléyì tì wòn ó sún, tì wòn ó b’èjé n’ìtàn wòn
Èbò ganó ní ganó ó sé
Òwó èjé kàn òwó èjé kàn
T’àwà nsè l’òsú yí
Ifá jè ó d’òmò.
According to this ifa stanza, I don't think it's a taboo for a woman to touch their orisha while on their period, the only thing is that she needed to bath before going or touch the orisha because if you look at the first line ifa says "ina papa lo bale to mo Roro" that is the plain street touches ground and was clean.
No comments:
Post a Comment