Sango Olukoso
Akata yeri yeri
Arabambi Oko Oya
Alaafin, ekun bu, a sa
Eleyinju ogunna
Olukoso lalu
Ina l’oju Ina l’enu
A ri igba ota, sete
O fi alapa segun ota re.
Sango Olukoso,
Akata yeriyeri,
Arabambi oko Oya,
O duro nilo, o kan lo,
Arabambi ara Oyo Moko,
Eeyan to njijo Sango
Ti o japa monu,
Abuku Sango ko,
abuku iru won in....
No comments:
Post a Comment