Aaka = Hedgehog
Àgbọ̀nrín = Deer
Agẹmọ, ògà = Chameleon
Àgódóńgbò = Colt
Àgùnfọn = Giraffe
Àkekè = Scorpion
Àkókó = Wood pecker
Akò = Grey Heron
Àparò = Bushfowl
Àwòdì, Àṣá = Kite
Ẹfọ̀n = Buffalo
Ẹ̀ga = Weaver
Erè, Òjòlá = Python
Erin = Elephant
Erinmi = Hippopotamus
Ẹtà = civet cat
Ẹtù, Awó = Guinea fowl
Etu, Èsúró = Duiker
Ewúrẹ́ = Goat
Ràkúnmí = camel
Ìbákà = Canary bird
Ìgalà = Bushbuck
Ìjàpá, Ahun, Alábahun = Tortoise
Ìnọ̀kí = Baboon or Mandrill
Ìràwò = Beetle
Kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ = Fox
Kìnìún = Lion
lámilámi = Dragonfly
Ọ̀fàfà = Tree hyrax
Ọ̀bọ = Monkey
Ológbò = Cat
Ọmọ-ńlé = Gecko Lizard/Wall gecko.
Òtòlò = Waterbuck
Òwìwí = Owl
Ọ̀yà = cane Rat/Grasscutter
Pẹ́pẹ́yẹ = Duck
Yànmùyánmú, ẹ̀fọn = Mosquito
Eranko bí ìmàdò/Àgbánréré = Rhinoceros
Ẹkùn/Ògìdán = Tiger
Àmọ̀tẹ́kùn = Leopard
Erinmi/Erinmilókun = Hippopotamus
Ìmàdò = Wild boar
Ìkokò = Hyena/Hyaena
Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ = Donkey
Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ abìlà = Zebra
Ìjímèrè = Brown Monkey
Egbin/Ẹtu/Olube/Èsúró = Antelope
Ọ̀wàwà = Cheetah
Ọṣà = Chimpanzee
Ọká = Rattlesnake
Sèbé = Cobra
Awọ́nríwọ́n = Alligator
Àléégbà = Monitor Lizard
Igún, Gúnnugún, Gúrugú = Vulture
Ológìrì = Palm bird
Àrígiṣẹ́gi = Wood- Carrier
Ọ̀kín = Peacock
Ọ̀kẹ́rẹ́ = Squirrel
Òkété = Pouch Rat
Èdú = Wild Goat
Àkúrákudà = Shark
Ekòló = Earthworm
Ẹyẹ-Orin = Songbird
Àparò = Partridge
Ìbákàsìẹ́ = Ass
Ẹyẹ-Ofu = Pelican
Ọsìn = Water Bird
Yanja-yanja = Sea Bird
Àdàbà = Dove
Paramọ́lẹ̀ = Viper
Pẹju-pẹju = Seagulls
Sọmídọlọ́tí/Olóyọ́ = Yellow-haired Monkey
Ẹyẹ-Iwo = Raven
Ìṣáwùrú = Fresh-water Snail
Ìgbín/Aginniṣọ = Snail
Ẹdun = Ape
Aláǹgba = Lizard
Alakasa = Lobster
Erè = African rock python
Ẹlẹ́dẹ̀-Igbó = Boar
Elégbèdè = Chimpanzee
Ojòlá = African rock Python
Kọ̀ǹkọ́ = frog
Ọ̀pọ̀lọ́ = Toad
Eégbọn = Tick/flee
Akàn = Crab
Oriri = Wild pigeon
Òòrẹ̀, Èèrẹ̀, Òjìgbọ̀n = Porcupine
Tanpẹ́pẹ́ = Blank-ants
Ọ̀kùnrùn = Millipede
Ajá-Ọdẹ = Hound
Lékeléke = Cattle-egret
Ọgòǹgò = Ostrich
Ikán, Ìkamùdù = White ant/Termite
Idi = Eagle
Oyin = Bee
Eṣinṣin/Eṣin = Housefly
Kòkòrò-Ojúọtí = Gnats
Ẹ̀lírí = Mouse
Abóníléjọpọ́n = Red-ants
Iná-Orí = Lice
Ìdun = Bedbugs
Alápàńdẹ̀dẹ̀ = Swallow
Irù, Eṣinṣin-ńlá = Gadfly
Akátá/Ajáko = Jackal
Ọ̀ọ̀nì = Crocodile
Eja-odò = Jelly fish
Àfèrègbèjò/ Àfè-ìmọ̀jò = A species of rat
Oka, is not a Gabon Viper but Rattlesnake.
ReplyDelete