Wednesday 5 June 2024

Yoruba Descriptive Female Names/Titles

(Orúkọ Àpọ́nlé àwọn Obìnrin)

(1). Aya - Wife

(2). Ìyá Ààfin - Palace mother/A Mrs.

(3). Aya Ọba (Ayaba) - Queen consort

(4). Ìyá Ọba (Ìyọba) - Queen mother

(5). Olorì - King's wife

(6). Omidan - Damsel / Young lady

(7). Ọmọge - Younger fashionable lady

(8). Ìyàwó - New bride

(9). Yèyélúwà - Mother of prosperity

(10). Ìyálé - First Wife

(11). Erelú - Female executive of power

(12). Ìyálọjà - Market Leader

(13). Arábìrin - Female comrade

(14). Àrẹ̀mọ - The first child (Female or Male)

(15). Ìyálájé - Female commercial Leader

(16). Abilékọ - Married woman

(17). Adèlèbọ - An older married woman

(18). Ìyálóde - Leader of all women

(19). Wúndíá - A maiden lady

Via ~ Adeboye Adegbenro.

No comments:

Post a Comment

Related Posts Plugin for WordPress, Blogger...