Good and bad walk together. Ifà talks from Òtúrúpọ̀n dìí as follows :-
Òrìṣà tó ṣe dúndùn ló ṣe àidùn
Adífá fún Ọ̀rúnmìlà tí yóó ṣ'ọkọ Ayọ̀
Tí yóó sì ṣ'ọkọ Ìbànújẹ́
Àt'èwe àt'àgbà
Ẹ y'ẹgba ẹ y'àtòrì
Ẹ bá wà lé ìbànújẹ́ lọ
TRANSLATION:
Òrìṣà who created joy also created sadness
Cast divination for Ọ̀rúnmìlà who will marry joy
And also marry sadness
Both the young and the old
Should bring out their canes and drive sadness away
The created song:
Ṣílẹ̀kùn ayọ̀ mi Ifá ṣílẹ̀kùn ayọ̀ mi
Ìbànújẹ́ ó jẹ́ kó jìnnà sílé mi
Wá múnúmi dùn Ifá Onílé ayọ̀
Ohun ayọ̀ mi májẹ̀ẹ́ kó pamí lẹ́kún
Open the door of joy for me, Ifá, the house owner of joy
Sadness should be far from my house
Please make me happy, Ifá, the house owner of joy
Don't let my joy turn to sadness
Stay blessed.
From Araba of Oworonsoki land Lagos, Nigeria
No comments:
Post a Comment