Looking at the Odu, "Òwónrín Ojó Òsè/
Òwónrín Ìká", cast for today's Ose Ifa, what
else can I say if not the importance of Òsè Ifá.
Just listen to the stanza
Òrúnmìlà ló l'òní
Ifá ló l'òla
Òrúnmìlà ló l'òtunla pélú
Ifá ló ni lojó mérèèrin Òòsà dáyé
Adífá fún Ojósè tí ńse omo bíbì inú
Àgbonmìrègún
Ifá t'óobá se mí tí mo fi l'ájé
Èmi yóó moò pè ó l'Ójósè tèmi
Ifá t'oóbá se mí tí mo fi l'áya/l'óko
Èmi yóó moò pè ó l'Ójósè tèmi
Ifá t'óobá se mí tí mo fi bímo
Èmi yóó moò pè ó l'Ójósè tèmi
Ifá t'óobá se mí tí mo fi kólé
Èmi yóó moò pè ó l'Ójósè tèmi
Ifá t'óobá se mí tí mo fi níregbogbo
Èmi yóó moò pè ó l'Ójósè tèmi
Òrúnmìlà òní l'Ojó Òsè........
TRANSLATION
Orunmila is the owner of today
Ifa is the owner of tomorrow
Ifa owns the day after tomorrow in addition
Ifa is owner of the four days of Oosa's
creation
Cast divination for Ojósè( Ifa worship Day),
child of Agbonmiregun
Ifa, if you endow me with money
I shall be callina vou mv own Oiósè ( Ifa
Èmi yóó moò pè ó l'Ójósè tèmi
Òrúnmìlà òní l'Ojó Òsè
Orunmila is the owner of today
Ifa is the owner of tomorrow
Ifa owns the day after tomorrow in addition
Ifa is owner of the four days of Oosa's
creation
Cast divination for Ojósè (Ifa worship Day),
child of Agbonmiregun
Ifa, if you endow me with money
I shall be calling you my own Ojósè (Ifa
worship day)
Ifa, if you endow me with a good wife/
husband
I shall be calling you my own Ojósè
Ifa, if you endow me with good children
I shall be calling you my own Ojósè
Ifa, if you endow me with a befitting house
I shall be calling you my own Ojósè
Ifa, if you endow me with all good things of
life
I shall be calling you my own Ojósè
Orunmila, TODAY IS OJÓ ÒSÈ( IFA WORSHIP
DAY).
Stay blessed.
By Araba of Oworonsoki
No comments:
Post a Comment