Àtẹlẹwọ́ f’ode ṣọ̀kan
Àtànpàkò ya ara rẹ̀ lọtọọ̀tọ̀
A dífá fun Olódùmarè, Atẹ́-ayé-matu,
Ọ̀yin fẹrẹ̀ fẹ̀rẹ̀, awo ilé Ọ̀rúnmìlà,
Kékeré ni mo ti j’olu
O dífá fún Oòduà, A-tẹ̀wọ̀n-rọ,
Ọ̀yin fẹrẹ̀ fẹ̀rẹ̀, awo Alaràn
A dífá fún gbogbo Ẹ̀-jẹ-n-din-lógún awọn isòrò
Ti nwọn yóó f’ori-k’ori l’alade-ọ̀run,
Láti fi idi ayé sílẹ̀
S’órí alagbalúgbú omi...
TRANSLATION OF OFUN MEJI:
Fingers came as a bunch on hand
While thumb almost disentangle from the bunch
Did Ifa consultations for Olodumare, the molder of the wholesome universe
Oyin fere fere, the sage of Orunmila dynasty
I became foremost at infant
Did Ifa consultations for Oodua, He that descended on chains to the earth
Oyin fere fere the sage or priest Alaràn house
Did Ifa consultations for all È-je-n-din-lógún, the cult
Those that will confer to download the secrets of the universe
On the high sea...
By Esuda Oracle Speaks
No comments:
Post a Comment