Looking at the Odù, Ogbè yẹ̀kú cast for today's Ọ̀sẹ̀ Ifá, I can say that there is nothing wrong for Babaláwo, Ìyáláwo/Ìyánífá and other Oníșẹ̀șe to join Ògbóni Fraternities if so desired except it's taboos for them. Listen to a stanza :-
Ogbè yẹ̀kú baba àmúlù
Orí ogbó orí atọ́ baba Ẹdan
Adífá fún Ilẹ̀ a bù fún Ẹdan
Ayé lè yẹ àwọn méjèèjì ni wọ́n ńdáfá sí
Ẹbọ ni wọ́n ní kí wọ́n ó ṣe
Wọ́n gb'ẹ́bọ ńbẹ̀ wọ́n rúbọ
Ayé yẹ Ilẹ̀
Ayé sì yẹ Ẹdan
TRANSLATION:
Ogbè yẹ̀kú father of Ifá combination
Longevity, father of ẹdan ( Òrìṣà of Ògbóni) Cast divination for Mother Earth and Ẹdan
Can life please the two of them?, reason for divination
They were advised to do ẹbọ
They both complied
Life pleased the Mother Earth
Life also pleased Ẹdan
May Ifá, Ilẹ̀ and Ẹdan make our lives pleasant.
From Araba of Oworosoki Land
No comments:
Post a Comment