Thursday, 20 July 2023

ASTRONOMY AND GEOGRAPHY IN YORUBA

Earth - Aye

Cloud - Ikuuku

Rain - Ojo, Eji

Storm - Iji

Sirius - Irawọ alẹ

Sea - Okun

Open water - Agbami

Ocean - Agbami Okun

Rock - Apata

Lagoon - Ọsa

Waterfall - Oṣọrọ

Lightening - Mọnamọna

Venus - Àgùàlà, Aja oṣu

Moon - Oṣu, Oṣupa

Sun - Oorun

Peak - Tente, Ṣonṣo, Gongo

Stars - Irawọ

Land - Ilẹ

Fog - Kùrukùru

Planet - Isọgbe oorun

Wave/Surf - Igbi

Dust storm - Ebutu, Eruku, Ẹbu 

Dawn - Afẹmọju, Ojumọ

Dusk - Aṣalẹ

Realm/Domain - Orilẹ

Eclipse - Iṣijibo

Earthquake - Ọmimi Ilẹ, Isẹlẹ

Dyke/Bank - Bebe

Gale, Tempest - Ẹfuufu

Thunder - Apaara, Ara

Air - Atẹgun

Wind/Breeze - Afẹfẹ

Valley - Ijigọnrọn, Ipẹtẹlẹ

Field - Papa

Island - Erekuṣu, Adado

Mountain - Oke

Brook - Oteere, Oterere

Hill/Hillock - Okiti

Whirlwind/Tornado - Aaja

Spring/Fountain - Ṣẹlẹru

Crust - Eepa ilẹ

Desert - Aṣalẹ

Spume/foam - Eefó

Gully/Ditch - Iyara

Universe - Agbaye

Coast - Etikun

Pit - Iho, Ọfin

Boundary - Ibode

Border - Aala

Sandstone/Laterite - Yangi

Torrent - Àgbàrá

New moon/Crescent - Oṣule

Full moon - Aranmoju

Pool - Ọgọdọ

Cliff - Ẹbìtì

North pole - Igun ariwa

South pole - Igun guusu

Flood - Ẹkun omi, Omiyale

Phenomenon - Àdìtú

Harmattan - Ọyẹ

Bush/Woods - Igbo, Igbẹ

Forest - Ẹgan

Pond - Abata

Savanna/Plain - Ọdan

Grove - Igbalẹ, Oṣuṣu

Rainbow - Oṣumare

Ravine - Afonifoji

River - Odo, Ẹri

Lake - Adagun

Drought - Ọdá 

Comet - Irawọ abiru/oniru

Famine - Iyan, Ọgbẹlẹ

Mineral - Kùsà

Tide - Ọsa, Iṣa

Rays - Titanṣaan

Dew - Iri 

Seasson - Asiko

Ice/Hailstone - Yinyin

Dusk - Aṣalẹ

Plateau - Pẹtẹlẹ

Colony/Dependency - Ereko

Altitude - Ìga

Wilderness - Aginju

Humidity - Ọrinrin

Shower - Ọwara 

Swamp/Marsh - Ẹrẹ, Ira

Harbour - Ebute

Abyss - Ọgbun

Atmosphere/Void - Ofurufu

Slope - Idagẹẹrẹ, Gẹẹrẹ

No comments:

Post a Comment

Related Posts Plugin for WordPress, Blogger...