Wednesday 29 December 2021

Symbol of Ìṣẹ̀ṣe - Yorùbá Religion

This is how Ifá explains it:

- Iwájú Ọpọ́n

- Ẹ̀yìn Ọpọ́n

- Olùmú Ọ̀tún

- Olùkànràn Òsì

- Àárín Ọpọ́n Ìta Ọ̀run....

The Symbol is simply telling us about the Philosophical concept of the Four Cardinal Points (Igun Mẹ́rin Ayé) and its cosmological meanings as it was arranged and explained by Ọ̀rúnmìlà Baraà mi Àgbọnnìrègún through IFÁ - the esoteric language of OLÓDÙMARÈ, and which is the Centrality of the Existence of Humanity, Divinity, and the Cosmos.

Ifá says:

Ìbọrú

Ìbọyè

Ìbọ sísẹ

Iwájú ọpọ́n

Ẹ̀yìn ọpọ́n

Àarin gbùngbùn ọpọ́n - ìta abàyà gbà á 

Dífá fún Ọ̀rúnmìlà 

Níjọ́ ogun ayé mú un lọ́rùn dun dun dun 

Wọ́n ní kó rúbọ 

Kó fi ẹran ọ̀bọ bọ òkè ìpọ̀nrí rẹ̀ 

A ṣẹ́gun nígbà yí 

A ti ṣẹ́gun 

Ifá tí fi ẹran ọ̀bọ bọ́ lọ́wọ́ ogun.....

By Awo Ifatola Akinwunmi 

Source: The Power of ifa

No comments:

Post a Comment

Related Posts Plugin for WordPress, Blogger...