Wednesday 10 August 2022

ODU IFA OYEKU OGBE

Looking at the Odù, Ọ̀yẹ̀kú Logbè, cast for today's Ọ̀sẹ̀ Ifá, I can advise the ignorants to stop abusing Ifá for their own sake. Just listen.

Agílá awo ni

Agìlá awo ni

Ọ̀pá gilágilà awo ni

A fi ti ọmọdé, ọmọdé ṣubú

A fi ti àgbàlagbà, àgbàlagbà mì sẹ́yìn

Adífá fun Ẹgbẹ̀rin ọ̀gbẹ̀rì

Tí wọ́n ńbú Ikin l'ékùrọ́

Ẹgbẹ̀rin ọ̀gbẹ̀rì tí ńbú ikin l'ékùrọ́

Ọ̀yẹ̀kú logbè Ifá o rín wọn rín wọn

Agílá is a Priest

Agìlá is a Priest

Ọ̀pá(Staff) gilágilà is also a Priest

We use it to push a child, the child falls down

We use it to push an elder, the elder shakes backwards.

Cast divination for eight hundred(800)uninitiated abusing our sacred Ikin and calling it ordinary palm nuts

The 800 uninitiated, the ignorants abusing our sacred palm nuts and calling it ordinary kernel

Ọ̀yẹ̀kú logbè, Ifá laughed at their stupidity.

Those who have ears should listen.

Happy Ọ̀sẹ̀ Ifá today to you all. Stay blessed.

From Araba of Oworonsoki

1 comment:

Related Posts Plugin for WordPress, Blogger...