Apá òsì: Èyí wà fún ọkùnrin tó ti di Aláya nílé.
Apá ọ̀tún: Èyí wà fún àpọ́n lỌ́kùnrin.
Gígẹ fìlà síwájú: Èyí túmọ̀ sí ọkùnrin tí ayé ti su.
Ki fìlà ga gogoro: Tí ọkùnrin bá dé fìlà gogoro èyí ń ṣe àfihàn ìwà ìgbéraga.
Gígẹ fìlà sẹ́hìn: Èyí ń ṣe àpèjúwe ọkùnrin tí kò bìkítà nípa nǹkan kan..
Mo rọ gbogbo àwa ọkùnrin kí á máa kíyèsi bi a ti ṣe ń dé Fìlà wa láti òní lọ nítorí bí a ti ṣe ń rìn làá ń koni.
YORUBA TIMES OF THE DAY
ÒWÚRÒ.................. 6 - 10 am
ÌYÁLÈTA.................. 10 - 12 am
ÒSÁN..................... 12 - 4 P
ÌRÒLÉ..................... 6 - 7 PM
ÀSÁLÉ/ALÉ............. 7 - 10 PM
ÒRU...................... 11PM - 12 AM
ÒGÀNJÓ.................. 12 - 2 AM
ÀÀJÌN....................... 2 - 3 AM
ÀFÈMÓJÙ..................... 4am to 5am
Please educate yourself and your children
No comments:
Post a Comment