Looking at the Odù, "Ọ̀wọ́nrín Ọjọ́ Ọ̀sẹ̀ / Ọ̀wọ́nrín Ìká", cast for today's Ọ̀sẹ̀ Ifá, what else can I say if not the importance of Ọ̀sẹ̀ Ifá. In addition, it is incontestable that Ifá is the owner of all days. Just listen:-
Ọ̀rúnmìlà ló l'òní
Ifá ló l'ọ̀la
Ọ̀rúnmìlà ló l'ọ̀tunla pẹ̀lú
Ifá ló ni ọjọ́ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin Òòṣà dáyé
Adífá fún Ọjọ́sẹ̀ tí ńṣe ọmọ bíbí inú Àgbọnmìrègún
Ifá t'óobá ṣe mí tí mo fi l'ájé
Èmi yóó mọ pè ó l'Ọ́jọ́sẹ̀ tèmi
Ifá t'oóbá ṣe mí tí mo fi l'áya/l'ọ́kọ
Èmi yóó mọ pè ọ́ l'Ọ́jọ́sẹ̀ tèmi
Ifá t'óobá ṣe mí tí mo fi bímọ
Èmi yóó mọ pè ọ́ l'Ọ́jọ́sẹ̀ tèmi
Ifá t'óobá ṣe mí tí mo fi kọ́lé
Èmi yóó mọ pè ọ́ l'Ọ́jọ́sẹ̀ tèmi
Ifá t'óobá ṣe mí tí mo fi níregbogbo
Èmi yóó mọ pè ọ́ l'Ọ́jọ́sẹ̀ tèmi
Ọ̀rúnmìlà òní l'Ọjọ́ Ọ̀sẹ̀....
Orunmila is the owner of today
Ifa is the owner of tomorrow
Ifa owns the day after tomorrow in addition
Ifa is owner of the four days of Òòṣà's creation
Cast divination for Ọjọ́sẹ̀ ( Ifa veneration Day), child of Àgbọnmìrègún
Ifa, if you endow me with money
I shall be calling you my own Ọjọ́sẹ̀ (Ifa veneration day)
Ifa, if you endow me with a good wife/husband
I shall be calling you my own Ọjọ́sẹ̀
Ifa, if you endow me with good children
I shall be calling you my own Ọjọ́sẹ̀
Ifa, if you endow me with a befitting house
I shall be calling you my own Ọjọ́sẹ̀
Ifa, if you endow me with all good things of life
I shall be calling you my own Ọjọ́sẹ̀
Ọ̀rúnmìlà, TODAY IS ỌJỌ́ Ọ̀SẸ̀ (IFA VENERATION DAY).
Stay blessed.
From Araba of Oworosoki Land
No comments:
Post a Comment