Looking at the Odù, Ogbè Atẹ̀, cast for today's Ọ̀sẹ̀ Ifá, I can boldly say as follows:-
Nígbàtí àwọn aláwọ̀ funfun ńgbá Ifá mú
Kíni ẹ̀yin aláwọ̀ dúdú ńṣe?
When the whites are embracing Ifá
What are Adúláwọ̀ (blacks) waiting for?
My people, Ifá has captured the world.
I am not surprised when Ifá says in Ogbè Atẹ̀ as follows :-
Ajé ire làá pè l'ówó
Ìmọ̀ràn ìlẹ̀kẹ̀ làá pè l'ókùn
Àgbàdo gbọ́fá àgbàdo ò gbọ́fá
Kò jẹ́ f'ìrùkẹ̀rẹ̀ s'ọ́wọ́ ọmọ ẹlòmíì
Tó bá jí á fi lé ọmọ rẹ̀ téteté kiri oko
Adífá fún Ọ̀kànlénírínwó Irúnmọlẹ̀
Tí wọ́n ń lọ rèé ṣ'ọkọ Ayé rèé
Adífá fun Ọ̀rúnmìlà tí ń lọ rèé ṣ'ọkọ Ayé rèé
Ọ̀rúnmìlà nìkan ní ń bẹ lẹ́yìn tí ńṣẹbọ
Èé e èyí àrà
Ifá ńgbayé lọ ọ̀gbẹ̀rì ò mọ̀
TRANSLATION:
Good fortune is money
Combination of beads is treasure
Whether the corn is knowledgeable in Ifa or not
Horse tail will never be handed over to another child
But given to the biological child
Cast divination for 401 divinities
When attempting to marry Ayé rèé (the mother Earth)
Cast divination for Ọ̀rúnmìlà also planning to marry Ayé rèé (the mother Earth)
Only Ọ̀rúnmìlà complied with the injunction of sacrifice
Oh, this is wonderful, Ifa captures the world, the ignoramus is surprised.
Stay blessed.
From Araba of Oworosoki Land
No comments:
Post a Comment