Ifá wípé:
Bí a bá gbọn aki dá gbọn
Bí a bá gọ̀ aki dá gọ̀
Ẹni ba gbọn títí, a gọ̀ síbi kan
Ẹni ba gọ̀ títí a gbọn síbi kan
Bí ọgbọ́n bá parapọ̀ a má ye dẹrun.
Dáa fún Oluwo Awomosu tó padà má kọ́ ifá lọwọ ọmọ a ná.....
Ifa wípé bí a bá jí ọgbọ́n ni kí a má kọ́ ara wa
Kí a má fi kùtùkùtù p'ilẹ̀ wéré.
Ifa- Owonrin-ogbe
Ifá says:
No one has the monopoly of wisdom
The cleverest has his limitations
The dullard too has limited scale of wisdom
organised knowledge is the basis of science
Divine for the leader of the Awos who ended up learning Ifá sermon from a childish person.
Ifá says, we should endeavour to share knowledge and wisdom when we wake in the morning, and not to set foundation of stupidity or madness in the dawn.
Extracted from- Owonrin-ogbe
Copyrights: © 2021
No comments:
Post a Comment