Wednesday 1 March 2023

OTURA OSE

Aṣèbàjẹ́ ṣe bí 

T'òun là ńwí 

Aṣeburúkú ẹ kú 

Ara á fuu 

Ẹ jọ̀ọ́ rẹ̀ 

Ẹ jẹ́ ó máa sá

Ìwà wọn 

Ni yíò máa lé wọn kiri

Día fún aníwọníkùn (aláìṣọ̀ótọ́) 

Tí yíò máa bẹ̀rù 

T'ọ̀sán, t'òru

O jẹ́ hùwà ire 

Ò bá hùwà àtàtà 

Aníwọníkùn 

Kí o yéé sá kiri 

Bíi arúfin...

The unrighteous thinks

His matter is being discussed

The wicked lives 

In constant panic

Let him be ignored 

Allow him run helter skelter

Their behavior 

Will cause them restlessness

This was Ifa's declaration  

To the untruthful 

Who lives in constant fear 

Day and night

You'd better be of good character

You'd better live righteously

Ye unrighteous soul 

Quit running about 

Like a fugitive...

Ifa teaches us to imbibe the spirit of Ìwà pẹlẹ. We should strive to do good at all times.

Life is an echo. What you send out comes back to you. What you sow, you reap. What you give, you get. What you see in others exist in you. Remember life is an echo, it will always get back to you.

Oluwo Akomolafe Wande

No comments:

Post a Comment

Related Posts Plugin for WordPress, Blogger...