Tuesday 29 June 2021

Awon Eya Mejilelogun (22) ti a npe Orile'ede Yorùba omo Oduduwa

1. Yoruba-Ife.

2. Yoruba-Oyo.

3. Yoruba-Ohori (Benin Republic)🇧🇯

4. Yoruba-Ekiti.

5. Yoruba-Ife-Togo 🇹🇬

6. Yoruba-Oworo.

7. Yoruba-Akoko.

8. Yoruba-Ijesa.

9. Yoruba-Owo. 

10. Yoruba-Akure.

11. Yoruba-Ondo.

12. Yoruba-Ikale.

13. Yoruba-Ilaje.

14. Yoruba-Egba.

15. Yoruba-Ijebu.

16. Yoruba-Awori.

17. Yoruba-Yewa.

18. Yoruba-Igbomina. 

19. Yoruba-Onko.

20. Yoruba-Owe. 

21. Yoruba-Omo okun.

22. Yoruba- Sierra Leone🇸🇱

Won tun nso ede Yoruba ni Cuba ati Brazil. 

Awon ọmọ wa gbudọ máa kọ èdè Yorùbá lati ile iwe alakobere.

No comments:

Post a Comment

Related Posts Plugin for WordPress, Blogger...