Sunday 13 December 2020

OGBÈ PẸ̀LẸ́ (Corpus of Easiness)

Ọrúnmìlà hí pẹ̀lẹ́-pẹ̀lẹ́

Mi pẹ̀lẹ́-pẹ̀lẹ 

Bara-mi-Àgbọniregun

Hí pẹ̀lẹ́-pẹ̀lẹ 

Ni ojú ńmọ́.

Ọrúnmìlà hí pẹ̀lẹ́-pẹ̀lẹ́

Mi pẹ̀lẹ́-pẹ̀lẹ 

Bara-mi-Àgbọniregun

Hí pẹ̀lẹ́-pẹ̀lẹ́ 

Ni ilẹ̀ ǹṣú.

Igbá pẹ̀lẹ́ 

Kìí fọ́ 

Àwo pẹ̀lẹ́ 

Kìí fà ya 

Ohun a fi ẹ̀lẹ̀ mú 

Kìí bàjẹ́ 

Ohun a bá fi agbára mú 

Níí le koko bí ọta.

Hárá-hárá gbì 

Ni a ngbọ́ 

Ẹnìkan kìí gbọ́ 

Pẹ̀lẹ́-pẹ̀lẹ́ gbìì.

Ò ní ẹ̀yìnkùlé Àùrẹ̀ 

Mà ni wọ́n ti ńgbé òkú 

Alágbára kọjá o.

Ifá ní kí a lọ ṣe pẹ̀lẹ́-pẹ̀lẹ́!

Translations:

Orunmila said with ease 

With ease; I repeated 

Bara-mi-Àgbọnìrègún 

He said the day breaks 

With ease.

Ọ̀runmila said with ease 

With ease; I responded 

Bara-mi-Àgbọnìrègún 

He said the sun sets 

With ease.

A calabash handled with ease 

Will never break 

A plate carried with ease 

Will never fracture 

What we tend with ease 

Will not rupture

That which is handle with force

Is as tough as stone.

Impatience leads 

To a sudden fall.

No one falls 

With an easy ride.

A dirge for the Mighty 

Will be sung 

Passing through the backyard

Of the Meek.

Ifá admonishes us to imbibe the virtues of easiness. 

Everything happens at its appointed time. The bitter truth is, you cannot force the hand of time. 

You are but an infinitesimal

part of the entire cosmos. 

At the appropriate time, everyone will be served what he deserves. You can only rush things at your own peril.

OGBÈ PẸ̀LẸ́

By Oluwo Akomolafe Wande

Copyrights: © 2020

No comments:

Post a Comment

Related Posts Plugin for WordPress, Blogger...