Pages

Saturday, 4 October 2025

Àwọn Olúbàdàn Tó Ti Jẹ Sẹ́yìn

(1). Lágelú (1820).

(2). Baálẹ̀ Máyẹ̀ Okùnadé (1820-1826)

(3). Baálẹ̀ Oluyendun Labosinde (1826-1830).

(4). Baale Lákanlẹ̀ (1830-1835).

(5). Basorun Olúyọ̀lé Ojaba (1835-1850).

(6). Baale Oderinlo Opeagbe Idiomo/Kure (1850-1851).

(7). Baale Oyesile Olugbode Ita Baale (1851-1864).

(8). Ba’ale Ibikunle (1864-1865).

(9). Basorun Ogumola Mapo (1865-1867).

(10). Balogun Beyioku Akere Onitamperin (1867-1870).

(11). Baale Orowusi (Awarun) Kobomoje (1870-1871).

(12). Aare Oladoke Latoosa Oke-Are (1871-1885).

(13). Balogun Ajayi Osungbekun Kobmoje (1885-1893).

(14). Baate Fijabi 1 (Omo Babalola) Oritamerin (1893-1895).

(15). Baale Osuntoki Olusun Agbeni (1895-1897).

(16). Badorun Fajimi (Yerombi) Oranyan (1897-1902).

(17). Baale Mosaderin Sunlehinmi Oranyan (1902-1904).

(18). Baale Dada Opadare Mapo (1904-1907).

(19). Basorun Sumonu Apanpa Isale-Osi (1907-1910).

(20). Baale Akintayo Awanibaku Elenpe Bere, Aboke (1910-1912).

(21). Baale Irefin (Omo Ogundeyi) Oke Ofa Babasale (1912-1914).

(22). Baale Shitu (Omo Are Latosa) Oke Are (1914-1925).

(23). Baale Oyewole Aiyejenku Omo Foko Oke Foko (1925-1930).

(24). Olubadan Okunola Abaasi Alesinloye Isale Ijebu (1930-1946).

(25). Olubadan Fagbinrin Akere II Oritamerin (1946).

(26). Olubadan Oyetunde I Eleta (1946).

(27). Olubadan Akintunde Bioku Oleyo, Oranyan (1947-1948).

(28). Olubadan Fijabi II Oritamerin (1948-1952).

(29). Olubadan Memudu Alli Iwo Gbenla (1952).

(30). Olubadan Igbintade Apete Oke Ofa (1952-1955)

(31). Oba Isaac Babalola Akinyele Alafara (1955-1964).

(32). Oba Yesufu Kobiowu Oranyan (1964)

(33). Oba Salawu Akanbi Aminu Adeoyo (1965-1971).

(34). Oba Shittu Akintola Oyetunde II Eleta (1971-1976)

(35). Oba Gbadamosi Akanbi Adebimpe Odinjo (1976-1977).

(36). Oba Daniel Tayo Akinbiyi Elekuro (1977-1982).

(37). Oba Yesufu Oloyede Asanike IdiAro (1983-1993)

(38). Oba Emmanuel Adegboyega Operinde Isale Ijebu (1993-1999).

(39). Oba Yinusa B. Ogundipe Arapasowu I Oranyan (1999-2007).

(40). Oba Samuel Odulana Olugade I (2007-2016).

(41). Oba Saliu Akanmu Adetunji (2016-2022)

(42). Oba Lekan Balogun (2022-2024)

(43). Oba Owolabi Olakulehin (2024-2025)

(44). Ọba Ràṣídì Ládọjà ni Ọba Kẹrìnlélógójì tí yóò gorí àpèré àwọn bàbá ńlá wọn.

No comments:

Post a Comment