But - Ṣugbọn
Except - Ayafi
Nevertheless - Sibẹsibẹ
Whatever - Ohunkohun
Precisely - Gangan
Very much - Gidi gaan
Unless - Afi
Likewise - Bakanaa
Then - Lẹhinaa
O 'right' - O tọna
O 'wrong' - Ko tọ/Ko tọna
Because (of) - Ni'tori (pé)
Mo 'Like' - Mo fẹran, Mo nifẹ
Even - Paapaa
Although/Though - Botilẹjẹpe
Especially - Agaga
Worry - Iyonu
Ma 'worry' - Ma ṣe'yọnu
Sincerely - Ni Tọkan/ Tọkantọkan
So - Tori naa
Ṣe 'mistake' - Ṣe Aṣiṣe
Most especially - Paapaa julọ
A must/Compulsory - Pon/Kan Dandan
Mo 'pass/succeed' - Mo yege
Mo 'fail' - Mo Kùnà
Ma 'rush' - Ma 'kanju'
Of - ti | Alaafin 'of' Oyo - Alaafin Oyo/Alaafin ti Oyo
How come? - Bawo loṣejẹ?
Need - Nílò
Force/By force - Ipá/T'ipá
Help - Iranlọwọ/Ìrànwọ
Anybody - Ẹnikankan
O 'pay' mi - O san mi
Whoever - Ẹnikẹni
Mo 'appreciate' - Mo Mọrírì
Anyone - Ẹnikankan
Anything - Eyi kankan / Eyikeyi
Anyhow -Lọnakọna
Mo 'try/attempt' - Mo Gbiyanju
No matter - Botilewu
Separately - Lọtọọtọ
O 'different' - O yatọ
For real? - Ṣe Lotitọ?
Anyway - Lọnakan ná
Whichever - Eyiowu
Since ti- Niwọn ti / Niwongba ti
Normally - Ni dede
Still - Sibẹ
Aside from - Yatọ si
Ko 'Easy/Simple' - Ko rọrun
Actually - Lootọ/Ni tootọ
Better - San ju, Dara ju
O wa 'important' - O ṣe pataki
Easily - Irọrun
O 'better' - O suwọn
Disappointment - Ijakulẹ
Exactly - Ni pato
O 'bad' - O buru
Mo 'understand' - Mo l'òye
Advice - Imọran
Really - Gaan
O wa 'okay' - O dara bẹẹ
Very - Gidi
Ko 'serious' (person) - Alawada/Oniyeye ni
Last time - Igbakẹyin
Previous time - Eṣi
At once/Immediately - Lẹsẹkẹsẹ
Instantly - Lọgan
Mo 'send' - Mo (fi) ranṣe
Wa ni 'standby' - Lugọọ
O 'fine' - O dara/rẹwà/lẹwa.
Yoruba Intelligence Network
No comments:
Post a Comment